Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.

Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.

Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.
Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà púpò.
Àwòrán yí mà rewà púpò, ìran méta yí sì wuni púpò jù.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo