Home / Àṣà Oòduà / Ewo nkan tí àwon èèyàn se fún àwon olè meta tí won jí kòkò obè.

Ewo nkan tí àwon èèyàn se fún àwon olè meta tí won jí kòkò obè.

Gégé bí ò n lò èro ayélujára( Facebook) tí ó pin àwòrán àwon òdókùnrin méta yí tí a gbó wípé won sì wà ní ilé-èkó girama ni won fi ìyà je won tí won sì so won kó sí ojú fèrèsé…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo