Home / Àṣà Oòduà / Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.

Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.

Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá.
Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi lówó nínú kànga ní iwájú ilé won, nígbà tí ó rí àwon oní jàgídíjàgan ní Itafaji, ní ìpínlè Eko .
Bàkan náà, látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá ló mu féré ge nígbà tí ó rí won, èyí sìni èsè rè tí won fi mu láti tì mólé.
Gégé bí won se so, won ní ó wà lára àwon oní jàgídí jàgan tí ó sá lo, gbogbo wàhálà àwon ará àdúgbò ló sì jásí asán láti jékí won fi sílè, báyìí ni won se mú omo yí àti ìyá rè lo.

 

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo