Home / Àṣà Oòduà / Òòsà Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash, níbi tí ó ti wo aso tí àyà rè hàn.

Òòsà Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash, níbi tí ó ti wo aso tí àyà rè hàn.

   Gbajúgbajà tí olórun fún ní èbùn tí ó bùáyà, tí a mò sí òòsà obìnrin ti ilè Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti Nabila Fash pèlú àyà rìwòwò tí olórun fún lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó ìbílè Oritsefemi ní Lekki ní ìlú Eko.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo