Home / Àṣà Oòduà / Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.

Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.

Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè.
Kí olórun te sí aféfé rere.
Kí á sì má rí irú rè mo.

About Awo

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.