Home / Àṣà Oòduà / Adebori ilu loruko tia pe ifa…

Adebori ilu loruko tia pe ifa…

Adebori ilu loruko tia pe ifa, Isinmi obarakale loruko tia pe orisala, Akorere wa bami loruko tia pe eyin iya mi osoronga, Meta niyin ni ojo ti e ti ikole orun bo wa sile aiye. Emi Olabisoyemansur ni pe yin loni o, nitori ara mi ati awon ore mi otito ati gbogbo omo egbe Ifa University wipe ki e bawa segun gbogbo ota wa patapata, ihoho la wa, ki e wa da aso ola bowa, ki e ma se na wa pasan aiye, ki e fi owo tiwa wo wa.

 

Ase !!

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...