Home / Àṣà Oòduà / Àgbàrá òjò ti gbalé gbalè ní ìlú ilé-ifè ní àná tí Òpò akékòó kò sì rí àyè lo sí ilé-èkó.

Àgbàrá òjò ti gbalé gbalè ní ìlú ilé-ifè ní àná tí Òpò akékòó kò sì rí àyè lo sí ilé-èkó.

   Gégé bí a ti mò wípé ilé-ifè jé ìlú tí ilé-èkó gíga wà, tí ó sì kún fún àwon akékòó bíi àwon akékòó ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university (OAU) àti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Oduduwa university ilé-ifè (OUI).

Yorùbá bò wón ní àgbàrá òjò kò ní òhun kò n’ílé wó sebí onílé ni kò ní gbà fun, àgbàrá òjò eléyìí ti w’olé nítorí àwon ará ilé ti gbaa láyè tí ó pò.
E má jé kí á k’ólé s’ójú àgbàrá mó a kò a ò gbó, kí á má dalè sí ojú àgbàrá mo, a kò a ò gbà. Erù àwon akékòó tó sòfò ló pò, ìwé èrí àwon míràn tilè ti bómi lo .
Kí elédùmarè sàánú wa , kí ó má jé kí á ríjà omi.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo