Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè.
Gégé bí ìwé ìròyìn Punch se so, Miracle jé omo bíbí ilú Agenenbode ní Etsako ìjóba ìbílè ìwó oòrùn ti ìpínlè náà, ta omo rè sí ilé àwon omo òrukàn fún élegbérún lónà igba náírà (#200,000) .
Miracle so wípé won ti òhun ni láti ta omo náà nítorí àìlówó lówó, àìrí nkan je .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo