Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

    Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti lò wà ní agbede méjì esè rè.

E wo àwòrán n’ísàlè .

About Awo

One comment

  1. Ere ti won se dun ju lo je ki o gbagbe re sibe

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo