Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán okò Mercedes Benz tí Obafemi Awolowo fi se ìponlogo ní ìgbà tí ó fé lo fún Ààre orílè èdè Nàíjíríà.

Àwòrán okò Mercedes Benz tí Obafemi Awolowo fi se ìponlogo ní ìgbà tí ó fé lo fún Ààre orílè èdè Nàíjíríà.

Obafemi Awolowo tí ó jé ògbóntarìgì àti adarí àwon olósèlú, tí ó sì kó iPa takuntakun láti jé kí orílè èdè yí di olómìnira.
Làra àwon ohun tí ó wà ní ibi tí won kó nkan ìsèńbáyé sí tí a mò sí Museum, ni okò tí a mò sí Mercedes 230:6.
Okò yí ni Awolowo lò láti fi se ìponlogo àti láti fi rin gbogbo ìrìn àjò ní odùn 1979 àti 1983, tí okò náà jé ríra ní odún 1970….

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo