Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí Annie Idibia yà tí ó tún yo ní àrà òtò nínú aso ìbílè tí ó wò tí ó sì se ara l’óge.

Àwòrán tí Annie Idibia yà tí ó tún yo ní àrà òtò nínú aso ìbílè tí ó wò tí ó sì se ara l’óge.

   Òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà tí ó tún jé ìyàwó 2baba tí ó jé olórin nlá, olorì Idibia dàbí egbin lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W àti Adesua ní ojó ìsinmi tí ó kojá.

Mo dàgbà tán èwe wù mí, nse ni ó dàbí eni wípé ó tún n kéré si.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo