Home / Àṣà Oòduà / Àwon agbésùmòmí Boko Haram pa àwon àgbè àti àwon ará ìlú ní Borno.

Àwon agbésùmòmí Boko Haram pa àwon àgbè àti àwon ará ìlú ní Borno.

Ókéré jù àwon ènìyàn méèdógún (15) ni a gbó pé àwon agbésùmòmí Boko Haram pa nígbà tí won kolu ara won. Ìròyìn tí Orísun àwon figilanté gbé ni wípé òpò àwon ará ìlú ní won sì ń wá léyìn Ìsèlè tí ó selè ní Jakete ní ìjoba ìbílè Konduga, agbègbè kan ní ìpínlè Borno. Ní kété agogo méwàá òwúrò àná ni won yín ìbon pa wón nínú oko won, tí a sì ń wá àwon obìnrin àgbè méfà.

Orísun àwon figilanté ti ìbílè náà jé kí ó di mímò wípé àwon àgbè náà gbìyànjú láti bó sùgbón agbára won kò ká àwon agbésùmòmí yìí…

Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo