Home / Àṣà Oòduà / Awon foto ayeye isinku Mama HID Awolowo

Awon foto ayeye isinku Mama HID Awolowo

Eyi ni die lara awon foto to jade nibi eye ikeyin ti won se fun Mama HID Awolowo eni ti won pada sin lojo karunlelogun osu kokanla odun yii, 25/11/15. E tesiwaju lati wo awon foto to ku.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo