Home / Àṣà Oòduà / Ay Makun àti Aliko Dangote níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki .

Ay Makun àti Aliko Dangote níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki .

Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè.

Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo