Home / Àṣà Oòduà / Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.

Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.

Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.Àwòrán rí ó rewà níbi tí àwon egbé oko (Banky W) ti n se àdúrá fún òré won tí ó n lo sí ìgbé ayé tuntun.
Èyí fi han wípé ìfé tí ó rinlè wà ní àarin won.
Èyí da àbí kò da.

About Awo

One comment

  1. After that you all slap the bololo and say amen

Leave a Reply to Dafe veta Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo