Home / Àṣà Oòduà / Ejo se ebi omo ni abi ti baba

Ejo se ebi omo ni abi ti baba


Baba kan wa obi omo kan kunrin kan osope omo ohun kogbodo losi puplic school nitori ko le gbo oyinbo dada baba yii ni alejo ni ojo kan osofun omo yii ko lobu omi wa baba unba ore re soro nigba ti omo bomi de oso fun baba wipe omi re oo baba sope gbe lemi lori be ni omo ba da omi le baba lori ejo ta lo jebi

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...