Home / Àṣà Oòduà / Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).

Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).

Ni Àná tí ó jé ogbòn-ojó osù keje odún 2018, ni eka-èkó ìmò àti Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò.

Òjògbón Wole Soyinka kò gbéyìn rárá Baba náà péjú pésè níbi odún náà.

Àsèyí se àmódún. (Àse).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo