Home / Àṣà Oòduà / Ènìyàn tí ó n gbé inú èkú láti ojó yìí tí a kò mò tí ó n jé lágbájá, àwòrán è rèé.

Ènìyàn tí ó n gbé inú èkú láti ojó yìí tí a kò mò tí ó n jé lágbájá, àwòrán è rèé.

Okùnrin kan tí ó n gbé inú èkú fohún bí egúngún tí a mò sí lágbájá ni àwòrán hàn ní ìsàlé yí fún ànfààní àwa tí a kò da mò.

Gbajúgbajà olórin a kó ni l’ógbón ni Lágbájá àwòrán rè rèé yìí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo