Home / Àṣà Oòduà / Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita

Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita

Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii:

“Walaaahi!
Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC.
Eyin o gbagbo?

O daa naa, ipo minisita wo ni won fi okunrin yi, eni to f’emi ara re wewu lati fese rin lati ilu Eko lo siluu Abuja nitori ti Aare Buhari ati egbe oselu APC bori ibo.

Mo fe fi asiko fun aare orileede yii, Muhammadu Buhari ati egbe oselu APC ni gbedeke ojo meje lati wa ipo kan fun okunrin yii tabi ki won da ileese ijoba kan ti yoo maa ri si “Irin-are” sile. Ki won si fi maanu yi se olori re.

Bi bee ko! E ma jee ki n so nnkan ti yoo sele. Nitori, maa mobilaisi lati yo Ibadan kuro lara orileede Nigeria ni o.”

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo