Home / Aarin Buzi / “Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo

“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo


Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). “Eyan Mayweather” ni yoo ma se awo eleekarun ti alase YBNL yoo ma gbe sita lati bi odun marun-un seyin to ti n se awo bo. Awon orin bi mokanlelogun (21) ni yoo ma ba awo orin tuntun naa jade eleyii ti Bobo, Melo Melo ati Lagos Boys yoo ma wa lara won. Eyan Mayweather E ma gbagbe wi pe Femi Solar naa n mura lati gbe fidio awo orin re tuntun jade. E le wo die ninu fidio orin naa NIBI

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*