Home / Àṣà Oòduà / Flavour ti fi èbùn olórun hàn l’ára rè nínú àwòrán tí kò ti wo aso tí ó yà.

Flavour ti fi èbùn olórun hàn l’ára rè nínú àwòrán tí kò ti wo aso tí ó yà.

     Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ó sì pamo jo bí edá, ó kúkú dún béè , bí ó tilè jé wípé ó pe ara rè ní “Ijele” tí àwa kò mo ìtumo rè àbi tani ó mò ó? Ó kù sí owó èyin Igbo e bá wa tu.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo