Home / Àṣà Oòduà / Ìlò wèrè aso Okrika (aso tí won ti lò rí).

Ìlò wèrè aso Okrika (aso tí won ti lò rí).

   ‘Okrika’ ni ònà tí àwon ènìyàn Nàjíríà n gbà pe aso tí won ti wò rí, tí won sí wo ìlú. Nígbà tí àwon nkan ti sa èyí tí ó dára níbè àwon kan kò ní aso tí won sì n wo àsàkù aso…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo