Home / Àṣà Oòduà / Juliet Ibrahim sí orékùnrin rè, Iceberg Slim, “mo dúpé wípé o gbà mí pèlú sùgbón mi.

Juliet Ibrahim sí orékùnrin rè, Iceberg Slim, “mo dúpé wípé o gbà mí pèlú sùgbón mi.

    Juliet Ibrahim ti wà nínú agbami ìfé, nse ni ó dàbí pé ó ti pàdé adé orí rè.

Òsèré kan ní orílè èdè Nàíjíríà ti fi èhónú rè hàn sí afòròdárà (rapper) kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Iceberg Slim ní orí èro ayélujára .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo