Home / Àṣà Oòduà / Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú

Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú

Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú
Láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Abajade ipade ile igbimo asoju to wa ni Abuja ni “a kuku joye san ju enu mi ko ka ilu lo”. Won ni ki gbogbo awon olori eso aabo Naijiria lo sinmi nile. Won ni ko si ogbon atinuda kankan fun enikankan won mo. Ki won lo, ki aaye le wa fun “awon odo iwoyi to mo ehoro iwoyi le”.


Won ni ko si ohun meji to fa eleyii bi ko se eto aabo ilu yii to n buru sii lojoojumo. Won ni agbara won ko ka awon onise ibi yii.
Koda, ni ile igbimo asofin agba, Seneto Abaribe ni ki Aare Muhammadu Buhari tile maa lo nitori pe oun ati egbe APC ko mo eyi to kan mo. O ni ona abayo ko si fun won mo.


Bi o tile je pe eyi fa tita ohun si ara eni laarin awon egbe oselu APC ati PDP, koda ile ise Aare naa da sii. Won ni Abaribe ko ni enu oro rara nitori pe egbe re naa lo ba ilu yii je de ibi to baje de. Won ni ko rorun lati tun nnkan se bi o se rorun lati ba nnkan je.

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo