Home / Àṣà Oòduà / Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.

Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.

E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa.

Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ó súré tèle wa, mo ti è fé mò gan. Àti àwon( Òré mi tí ó ti n’íyàwó) jé éri si èyí, wípé àwon omoge ń du àwon tí ó ti n’íyàwó, wón gbàgbó wípé àwon máa ń se ìtójú obìnrin dáadáa, e jòwó Sé òtító ni èyí?

Obìnrin  Lásán…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo