Home / Àṣà Oòduà / Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Olúsèse, Àràbà àgbáyé ti dágbére wípé Ó dígbà fún aráyé, baba ti lo rè é bá àwon baba ńlá rè ní ìwàlè àsà.

Ó mà se oo, ikú ti pa agbe kò le dáró, ó ti pa àlùkò kò le ko sùn, ikú ti pa lékélèké kò le k’efun, baba wa Olúsèse ti lo.

Àrólé òrúnmìlà se béè ó ròrun Alákeji, awo ooni Olódù mérìndínlógún se elèdè léyìn baba.

Omo Oòduà rere ń se elédè léyìn baba….

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo