Home / Àṣà Oòduà / Òdókùnrin yí ni ó ko “666” sí iwájú orí rè.

Òdókùnrin yí ni ó ko “666” sí iwájú orí rè.

   Bóyá láti jé kí àwon òré rè lórí èro ayélujára(Facebook) tèka wípé àwon féràn rè ni tàbí kí ó fi di gbajúgbajà. Òdókùnrin tí kò dàgbà jù, tí ó sì jé ò n lò èro ayélujára(Facebook), tí a mò sí Samuel Sammy-g ni ó ya àwòrán báyìí tí ó ko “666”sí iwájú orí rè .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo