Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni – 01.08.2016

Ogulutu Oro Toni – 01.08.2016

Hummmmmm were were odunyi tun pari lo re.
Humm Oya bi arare lere
Wipe lati ibeere odunyi tofi di akoko tawa.
Kilo ti gbese?????
Hummmmmm
‪Woo orewa‬
Nje o mope Olohun koda o lasan bi?
Maduro toraye gan oduro lasan.

gbiyanju lati gbe igbese loni,yio si dara fun ooo.

Ire ooo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...