Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni 18.08.2016

Ogulutu Oro Toni 18.08.2016

Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo
‪woo orewa‬
Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi?
Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm.
‎gbomi dada‬
Bisu eni bata nise leyan mo ndawo bo je kole ba bani kale…….

Ao ni teni tika ooooo…Ire ooo

King Ogulutu Oro

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo