Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016

Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016

Hummm bona kan o badi odamiloju pe ona Miran olela,iyen fun enito ba mo nkan ti nse.

Woo Orewa
Benikan ba sope sise re titan lodo ohun, mofe komope ose tie ni kose ti Olohun o, nise ni kode fila mowobe nitori riro nteniyan sise ntoluwa
Gbomi Dada
Eda lo nkanju ori okuku rebikan tori akunleyan ladayeba o
Mofe Koranti
Pe ao le sare koja akosile o, tori kosibi ase le sare to eyin bai lao fi gigise si…..se kirakita mo niwon ba ao ni waiye alaiye ooo ire ooo

 

King Ogulutu Oro

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo