Home / Àṣà Oòduà / Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga ifáfitì.

Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga ifáfitì.

Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga.

1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní dáadáa, láti mo ìlépa re tí ó jé wípé nígbà tí o bá se tán o kò ní fi àkókò re s’òfò.

2- ní ìlépa tó dáńgájíá.

3- tí o bá ní èbùn tàbí ohun tí o féràn láti ma se má fi àkókò s’òfò láti sin enikéni! Lépa ònà tìre.

4 – má jè é kí enikéni so fún o wípé “o kò le se é”.

5- Gbìn sínú okàn re má sì jé kí okàn re rè sí isé òòjó re : èkó lórí ara eni (self study), èkó àgbà (post grad study), isé re (courses), eré ìdárayá (sport), kíka ìwé (reading) Àpérò (seminar) ìrìnàjò (travelling), èdè (linguistic).

6- má gbé okàn lé ònà àtije kan, gbìyànjú láti ní ònà míràn.

7- tí o bá pinnu láti sisé l’ábé enikéni ó ye kí o mò wípé ìgbéga re ó dá lórí òsùwòn 40% fún isé kára kára àti 60% òsèlú tí ó sì jé wípé kò ní sú e….

Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo