Home / Aarin Buzi / Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara

Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara

Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. Bakan naa ni awon onise tiata kii fe e kuro nita boro. Gbogbo ona ni won si maa n gba lati gunrege loju awon onibara won.
Ju gbogbo, o se je ibaradi ni iya Simisoluwa gbesoke fun wa? Eleyii ga ju!

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo