Home / Àṣà Oòduà / Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’

Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’

Àwọn Dókítà láti ilẹ̀ China tó ṣẹ̀sẹ̀ dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus kò ní tọ́jú aláìsàn kankan.

Iléeṣẹ́ láti ilẹ̀ China to tó ṣe ojú ọ̀nà àti ojú irin( CCECC Nigeria), ló fi àtẹjáde náà léde pé àwọn Dókítà náà wá láti kó àwọn ohun èlò ìrànwọ́ tí iléeṣẹ́ náà pèsè fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wá láti China

Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’

Fẹ́mi Akínṣọlá

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.