Home / Àṣà Oòduà / Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó kéreké parí ilé-èkó gíga ifáfatì ti ìlú ìbàdàn (university of Ibadan).

Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó kéreké parí ilé-èkó gíga ifáfatì ti ìlú ìbàdàn (university of Ibadan).

Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó, Oba Lamidi Adeyemi kékeré, ti parí ifáfitì ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Ibadan tí a mò sí University of Ibadan.

Bí omo bá dára ká so, ó ye kí á yé olorì sí lóòótó.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo