Home / Àṣà Oòduà / Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.

Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.

Àwon olólùfé gbajúgbajà olórin tí a mò sí Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
Davido le jé eni tí àwon ènìyàn féràn sùgbón ìyan kò so pé ó kojá ìbáwí, tí ó bá ye kí á ba wí…

Gbajúgbajà olórin, pín àwòrán ara rè tí kò wo aso sí orí èro ayélujàra (instagram) lésèkesè ni àwon èèyàn ti ń bu tí won sì gbà á ní ìmòràn látàrí rírí àbùkùn kan tàbí méji nípa àwòrán náà.

Nígbà tí inú àwon kan kò dùn sí àwòrán tí ó yà s’ára àwon míràn gbà á ní ìmòràn kí ó lo fá irun abíyá rè tí ó ti kún

Continue after the page break for English Version

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo