Home / Àṣà Oòduà / Olùsó àgùntàn David Ibiyeomie gba okò bògìnì fún èbùn ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún márùnléláàdóta .

Olùsó àgùntàn David Ibiyeomie gba okò bògìnì fún èbùn ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún márùnléláàdóta .

     Gégé bí Innocent se so, olùsò àgùntàn rè pastor David Ibiyeomie ni won fún ní okò bògìnì tí ó wà ní ìsàlè yí gégé bi èbùn ojó ìbí rè, sé kò dùn gbó l’étí ni?.

Ó ye kí á rántí wípé gbajúgbajà olùsó àgùntàn tí o fi Port Harcourt se ibùgbé se ayeye ojó ìbí rè ní ojó díè séyìn…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo