Home / Àṣà Oòduà / Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.

Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.

      Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó mú ayé mi dára…..ìyáre n’ífè re …Enikeji ìyá rè”…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo