Home / Àṣà Oòduà / Omoni àti Nnamdi Oboli se ayeye ìrántí odún métàdínlógún (17) ìgbéyàwó won pèlú àwòrán tí ó ti pé.

Omoni àti Nnamdi Oboli se ayeye ìrántí odún métàdínlógún (17) ìgbéyàwó won pèlú àwòrán tí ó ti pé.

    Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won.

Won sì pín àwòrán tipétipé won…

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo