Home / Àṣà Oòduà / Osatura ni kini otito ?

Osatura ni kini otito ?

Emi ni ki ni otito ?
Orunmila ni otito ni oluwa orun to nto aiye
Ogbon ti eledumare nlo
Ogbon – nla, opolopo ogbon
Osatura ni kini otito ?
Emi ni ki ni otito?
Orunmila ni otito ni iwa eledumare
Otito ni oro ti kole subu
Ifa ni otito
Otito ni oro ti ko le baje,
Agbara – nla, ajulo, ire ailopin,
Adifa fun aiye
A niki won maa se otito
Ki awon omo araye le ma mo otito lati inu wa
Ki o si le ro won lorun lati maase otito.

TRANSLATION

Osatura asked what is truth ?
I asked what is truth ?
Orunmila said truth is the God that is guiding this earth
The wisdom of our creator
Great wisdom, much wisdom,
Osatura asked what is truth ?
I asked what is truth ?
Orumila said truth is the character of our creator,
Truth is the infallible word
Ifa is truth,
Truth is the unchangeable word,
Great power, unsurpassable, unending good,
Divined for earth,
We said they should speak the truth
So that men may know the truth from within,
So that it shall be easier for them to practice truth.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*