Home / Àṣà Oòduà / Simi kúnlè ní orí ìtàgé láti kí ògbóntarìgì olórin tí a mò sí Lágbájá, nígbà Ó ń dá àwon èèyàn lárayá lówó.

Simi kúnlè ní orí ìtàgé láti kí ògbóntarìgì olórin tí a mò sí Lágbájá, nígbà Ó ń dá àwon èèyàn lárayá lówó.

Simi tí síde ayeye tí Jannie, Jazz àti Whisky pè ní ìlú Abuja ní alé ojó náà, Simisola jungle ní orí ìtàgé láti kí eni ńlá, èníyàn pàtàkí àti gbajúgbajà olórin láti dá àwon èníyàn lárayá papò.

Ògbóntarìgì olórin tí Ó máa n gbé eégún tí èyí kà láyà náà kúnlè láti fa Simi sókè tí ó sì fà á móra láti gbe dìde.
Simi tí Ó pín àwòrán yí sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram rè, tí Ó sì ko síbè pé “àlá mi wá sí ìmúse láti pàdé gbajúgbajà olórin yí láti dá àwon èníyàn lárayá papò.

” lánàá mo pàdé ògbóntarìgì olórin, ìlú mòóká, mo sì gbádùn ayé mi” báyìí ni Simisola wi.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo