Home / Àṣà Oòduà / Tinubu, Modu Sheriff, Ben Bruce níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki.

Tinubu, Modu Sheriff, Ben Bruce níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki.

Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites ) ìpínlé…

About Awo

One comment

  1. Eto igbeyawo laye…Oluwami fi le le pelu ase ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo