Home / Àṣà Oòduà / Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún yí ó sì pa Davido láyò.

Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún yí ó sì pa Davido láyò.

Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo