Home / Author Archives: Awo (page 22)

Author Archives: Awo

Òkan l’ára àwon anamoyayà (civil defence officer) ni àwon fúlàní darandaran pa ní ìpínlè Benue tí won sì sin ín pélú omijé.

Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.

Read More »

Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán ...

Read More »

Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Baba ìsàlé egbé APC tí a mò sí asíwájú Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí ògbéni Rauf Aregbesola, Gómìnà ìpínlè Ondo, tí a mò sí Rotimi Akeredolu ní ìlú Ibadan ti fi tòwòtòwò gba olóyè Alao ...

Read More »

Arákùnrin kan tí won lé kúrò ní ilù òyìnbó wá sí orílé èdè Nàìjíríà nígbà tí omo rè obìnrin wà ní odún méjo (8) ti fi ara hàn nígbà tí omo rè kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè U.S.

    Yàtò sí wípé ó n kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti a mò sí ‘Morgan state university’, ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mò sí Esther Ayomide tún ní èbún pàtàkì tí ó n dúró ...

Read More »

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

   Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ...

Read More »

“Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.

   Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.

    Nígbà tí mo rí àwòrán yí ní orí èro ayélujára , mo kókó dúró ná mo wá bi ara mi ní ìbéèrè wípé kíni obìnrin fé nínú ìgbéyàwó tàbí lára okùnrin ? Léyìn òpò ìrònú àti òpò ìrírí ...

Read More »

E wo aso Ebuka níbi ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti ìyàwó rè, Adesua Etomi.

Òpò ni ara ti n yá tí won sì ti fi ojú s’ónà láti wo aso tí Ebuka ma wò ní òtè yí báwo ni ó ti è se ma rí nínú rè ni ìbéèrè àwon ènìyàn, bí ó tilè ...

Read More »

Àwòrán ìsìnkú Akékòó jáde ti ilé èkó gíga Nnamdi Azkiwe (UNIZIK) tí ó kú ní òsè mélòó séyìn.

Olóògbé Arábìnrin Amaka Ezeokoli tí ó kú ní òsè mélòó séyìn léyìn àìsàn péréte , se ni won ti sin-ín ní ojó Àbáméta (Saturday) ní ìlú tí won bi sí ní Ezioko ní ìjoba ìbílè Gúúsù ti Orumba tí ó ...

Read More »