Home / Author Archives: Awo (page 26)

Author Archives: Awo

Oba ti ilè Benin, Ewuare,ti kalè sí Abuja pèlú àwon olóyè rè fún àbèwò pàtàkì.

Oba ti ilè Benin, Aláse èkejì òrìsà, Oba Ewuare ti balè sí Abuja fún àbéwò pàtàkì. Oba tí àwon olóyè rè sìn lo sí Abuja ni won ti kí káàbò, àwon alága ìgbìmò egbé APC (All progressive Congress), John Oyegun ...

Read More »

Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntun

Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntum. Olórin, peter Okoye tí a mò sí Mr.P tí ó ti fi èkejì rè sílè, Paul Okoye àti alákoso won, Jude Okoye ti gba alákoso tuntun. Ó sì ti ...

Read More »

Tunde Demuren, Ebuka àti ìyàwó rè ti wo okò òfurufú (jet) láti lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W.

Gbajúgbajà ni, òtòkùlú ni, captain Tunde Demuren tí ìnagije rè n jé OAP, oko toolz ti gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán yí nígbà tí won wo okò òfurufú lo sí Capetown láti péjú pésè níbí ...

Read More »

Àwon onísé abe; bàbá kan ní orílé èdè Nàíjíríà àti omo rè obìnrin ti se isé abe lórí aláìsàn won .

Ò n lò èro ayélujára (Facebook) Bucandy Ayo Abubakar, tí ó jé onísé abe pín àwòrán ara rè àti bàbá rè àti bàbá rè onísé abe ti se isé-abe fún aláìsàn kan tí ó ní àìsàn “Appendix” ó sì ko ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.

Ìgbéyàwó eka-èkó (departmental weeding) ni, ìgbéyàwó àgùnbánirò ni tí ó bèrè láti e n lé di e pèlé, tí won wá di orè tímótímó eka-èkó tí won sì padà di olólùlé eka-èkó báyìí ó ti di ìgbéyàwó eka-èkó. Ihekuna Ann ...

Read More »

Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .

Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù . Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó ...

Read More »

olópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà látàrí aso ìwòkuwò tí won wò.

Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ...

Read More »

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè. Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare. Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú Ekan Egonmwa. Ó sì ti se ayeye ...

Read More »

Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.

    Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won. Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí ...

Read More »