Home / Author Archives: Awo (page 35)

Author Archives: Awo

Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.

  Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.

Read More »

Àwòrán bàbá àti àwon omo rè obìnrin méfà.

   Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà ...

Read More »

Gómìnà ìpínlè Eko ti sí ojú ère ” ASA AROKOLO” ní ogonlonto ní Ikorodu lánàá.

   Ère tí ó bù áyà tí ó fi àsà wa hàn ní Ikorodu ni Gómìnà ìpínlè Èkó ti báwa sí lánàá.

Read More »

E wo ojú Davido ní orí ìtàgé nígbà tí obìnrin náà fi ìdí rù ú .

   Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò ...

Read More »

Funke Akindele tún yo ní àrà òtò .

Funke Akindele tí gbogbo ayé mò sí Jennifer tún yo ní àrà òtò níbi àwòrán yí…

Read More »

Peter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.

    Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr P gbe sí orí èro ayélujára (Instagram) láti se ayeye ojó ìbí ìyàwó èkejì rè . Anita Okoye tí ó lé odún kan ní òní. Ó ko sí ibè wípé ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti ìyàwó rè Hausa yà.

   E gbe yèwò àwòrán tí ó rewà kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti olorì tí a mò sí Hauwa yà . Won sì se jómírégí.

Read More »

Alángbá nlá tí won pa fún obè aláta yéríyérí.

     Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook) se pin. Ó so wípé òun pa Àntà( Alligator) nláyí ní àárò yí òun sì n wá àwon èlò tí òun yóò fi si láti se obè aláta yéríyérí. È ...

Read More »

Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

   Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume . Olóògbé Lawretta ni won pa… Kí olúwa te sí aféfé rere … Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) . Olùkó àti ...

Read More »

E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.

E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè. O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.

Read More »