Home / Author Archives: Awo (page 7)

Author Archives: Awo

Òtúrá Òfún (Òtúráfùnún)

Àkúsàba Àyàndà Awo ilé Olúmẹ̀ri Àápáálá Ọmọ ilé san wón ó joko lọ Níjọ́ tí ń ṣọ̀gbọ̀gbọ̀ àrùn Tí ń najú aláì le dìde Olúmẹ̀ri Àápáálá làrùn ń ṣe Òún wá á le gbádùn gbogbo nǹkan òun lójú ayé òun ...

Read More »

Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.

Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè. Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà ...

Read More »

Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.

Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá. Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi ...

Read More »

Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè ...

Read More »

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná. Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.

Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn . Àwòrán ti aya ...

Read More »

Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè . Gboyega Oyetola ni ...

Read More »

Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé. Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí ...

Read More »

Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.

Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni ...

Read More »

Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.

Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù. ...

Read More »