Home / Author Archives: ayangalu (page 17)

Author Archives: ayangalu

Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde.

Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde. Ijuba. Doy reverencia. Ìdà kí si ònà ní nse ejó lè yínA’dífá’fún Esin ohun AgboTi wòn nse Awo losí ilé ...

Read More »

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú abínibí rẹ̀ nípìńlẹ̀ Bayelsa. Nínú ...

Read More »

Olè yabo báńkì: O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò

Olè yabo báńkì. O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò Bí ayé bá ń lọ sópin, àràǹbarà ìran lojú yóó máa rí. À bí kín ní ká tí pèyí sí pẹ̀lú bí arákùnrin òyìnbó onírungbọ̀ kan ṣe dédé yabo ilé ...

Read More »

Ìjà ìgboro bé̩ sìlè̩ lórí Sowore

Ogbeni Omoyele Sowore to je aja-fun-eto- omoniyan to tun je oludije du ipo Aare ni odun yi ni o ti wa ni ahamo awon agbofinro lati bii osu meta seyin.Ile-ejo ni ki o maa gba ile wa jejo sugbon ijoba ...

Read More »

Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì

Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo ti gbé Pásítọ̀ Alfa Babatunde tíí ṣe olùdásílẹ̀ Ìjọ Sòtítọbírẹ ní Ondo lọ Ilé ẹjọ́ léyìí tí ìwòye sì ...

Read More »

Ìròyìn Òwúrò̩ t’ò̩s̩è̩ yí

Read More »

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti DasukiLati owoYinka AlabiIjoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck ...

Read More »

Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami

Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.

Read More »

Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m

Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m Ariwo t’íjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ń pa lé àwọn tó jẹ ẹ́ ni gbèsè owó iná nìyí báyìí o. Ṣùgbọ́n lọ́tẹ̀ yìí kìí ṣe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ...

Read More »

Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè

Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...

Read More »