Home / Author Archives: ayangalu (page 66)

Author Archives: ayangalu

Iwure Owuro 02-04-2016

E MAA WI TELE MI : ……. *Edumare ma je ki n soore daran. *Oluwa ma je ki n gbalejo oran. *Edumare ba mi segun elenini. *Oluwa ran alaanu si mi. *Edumare gba mi lowo alaroka. *Oluwa dakun rojo ibukun ...

Read More »

Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi

A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni ...

Read More »

Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..

Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù, Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí. Àlékún owó, Àlékún ogbón, ...

Read More »

Owe Toni 27/03/2016

OWE TONI Bi o ti wu ki oju orun funfun to, sanma dudu yo wa ,,…………………,…………………………………………. No matter how bright the sky clouds will exist(challenges aren’t unusuall)

Read More »

Iwure Owuro 27/03/2016

:::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::: E MAA WI TELE MI : ……… *Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ogun aye koni bori mi. *Iji aye koni ja lu mi. *Inira ati idaamu, koni je temi. ...

Read More »

Oruko wo won Npe Kini yi ni Ile Yin ?

?

Read More »

Opele ide (brass divination chain)

Opele ide (brass divination chain)

Read More »

Ti o ba ni #500, osi fe da ina okele, Bawo Ni wa Sena ?

TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele ‪#‎antyfolashadealawada‬

Read More »

Iwure Owuro 21/03/2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...

Read More »

Ewi Toni – 20.03.2016

Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...

Read More »