Home / Author Archives: oodua (page 10)

Author Archives: oodua

Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun

E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa.  Ase. Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba ...

Read More »

Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai

Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a ...

Read More »

Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki

Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi  ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...

Read More »

Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko

Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...

Read More »

Oserebirin wo leyii, Se e damo bi??

Read More »

E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan

Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan ...

Read More »

Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi

Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...

Read More »

Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti

Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...

Read More »

Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye

Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. ...

Read More »

IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo

Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.

Read More »