Home / Author Archives: oodua (page 4)

Author Archives: oodua

Ewi Toni: Atoto arere

Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...

Read More »

‪Laye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)

Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE). …….. Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko ...

Read More »

Iwure Owuro – 18/03/2016

E MAA WI TELE MI : …… *Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi. *Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi. *Ogun idile ko ni bori mi. *Ki osu yii to ...

Read More »

Emi Ibinu

Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu. Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje. Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ...

Read More »

Regina Chukwu lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Taiwo Ibikunle lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Koffi lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Tayo Adeleye lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Ifankaleluya lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Sunkanmi lori eto Gbajumo Osere

Read More »